Folake Oladosu
Àjàyí ńlọ sí ilé-ẹ̀kọ́. Inú rẹ̀ dún púpọ́ láti rí Doyin, Àdùkẹ́ pẹ̀lú Taíwó àti Kẹ́hìndé. Olùkọ́ Àjàyí, Ìyá-Àfin Ọ́lálẹ́yẹ ní ìkónimọ́ra púpọ̀.Ajayi is heading to school. He is excited to see Doyin, Aduke, together with Taiwo and Kehinde. His teacher Mrs Olaleye is especially friendly.